Publications

1 - 5 of 5

    Tbon

Read More>>

    

Read More>>

    Iwe mimo Ifa Esin Akoda Olodumare

Die ninu ohun ti aoba pade ninu iweyi ni 1,Iboni osan ti kokodi oru, nile aye.?kin ni ofaa? 2,kin ni idi ti ope Ifa kofi leehu nilu Osogbo.bawo ni oruko odo okoro koro ati ikin tu okun sewaye? Idahun si gbogbo ibeereyi wa ninu odu ifa idin ileke

2.Ejiogbe lojeki amo Ela omo Oyigi, se okan naa ni Jesu ati Ela tabi ojorawon ni?.Ewo ejiogbe ori kin in ni ese keji.3.Iru isewo ni Olodumare ran Oodua wase laye? Kin ni ojureri? Awon todi lowo iboni orowon jasi? Ejiogbe ese kin in ni. Otan lenu oku nikun.ireooo

Read More>>

    Iwe Mimo Ifa Esin Akoda Olodumare

Ìwé pàtàkì ni ìwé yìí, ọ̀kan nínú àwọn àgbà awo ilẹ̀ Yorùbá ló kọ ọ́, òun náà ni Akọ́dá Ìlú Ìbàdàn, Babaláwo Ọdégbọlá Ifálérè.

Èyi ni ìwé àkọ́kọ́ tí ó ní ẹsẹ méjì méjì lórí odù kọ̀ọ̀kan tí ó kó gbogbo odù já pátápátá tí ósì pàsẹ ifá dáadáa, tí ó yéni yékéyéké tí ó sì ní àkọtọ́ èdè Yorùbá tí ó yege.

Èmi Ọ̀jọ̀gbọ́n Wándé Abímbọ́lá fi tayọ̀ tayọ̀ júwe ìwé yìí gẹ́gẹ́ bíìwé tí a lè kà ní ilé ẹ̀kọ́ Girama tàbí Yunifásítì, mo sì kí Akọ́dá Awo Ìlú Ìbàdàn kú oríire, èyí kò ní jẹ́ àkọmọ, a ó kọ òmíràn, a ó sì rí ẹ̀mí lò ó, àlékún owó, àlékún ọmọ, àlékún àìkú baálẹ̀ ọrọ̀.

Read More>>

    Ìbágbépọ̀ Tọkọ Taya

Ìbágbépọ̀ Tọkọ Taya, 2014.

Ó dá lórí pàtàkì ìgbéyàwó àti ọ̀nà tí ìgbéyàwó kò fi ní máa túká mọ́.

Read More>>
Previous | Next
 

Contact Address

Stay in Touch

Distributors Contacts

12, Falere Odegbola Street, Off Alakaso Road,

Omi-Adio, Ibadan, Ido LGA, Oyo State, Nigeria.

Phone No: +2348054009431, +2347034208381

Email: info@odegbolaifalere.com

Website: www.odegbolaifalere.com

=> OAJ Book shop Dugbe, Ibadan, Oyo State. +2349189747423

=> Otunba Lekan Ajirotutu, NTA Ch 10, Lagos State.

=> Tubosun Oladapo, Lagos Garage, Iwo Road, Ibadan, Oyo State.

=> Odusote Book Shop, Oke-Bola, Ibadan.

 

=> Deji Medubi, UNILAG, Lagos State.

=> Ejiodi Home of Tradition, Alade Near Moniya, Ibadan, Oyo State.

=> Dr. Adeola Faleye, OAU Ile-Ife, Osun State.

=> Dr. Abiodun Agboola, OAU Ile-Ife, Osun State.

=> OAU Bookshop, Ile-Ife, Osun State.

=> U.I Bookshop Ibadan, Oyo State. 

=> 13, Elebuibon Street, Osogbo, Osun State

Subscribe to our Newsletter

Navigation