Ìwé pàtàkì ni ìwé yìí, ọ̀kan nínú àwọn àgbà awo ilẹ̀ Yorùbá ló kọ ọ́, òun náà ni Akọ́dá Ìlú Ìbàdàn, Babaláwo Ọdégbọlá Ifálérè.

Èyi ni ìwé àkọ́kọ́ tí ó ní ẹsẹ méjì méjì lórí odù kọ̀ọ̀kan tí ó kó gbogbo odù já pátápátá tí ósì pàsẹ ifá dáadáa, tí ó yéni yékéyéké tí ó sì ní àkọtọ́ èdè Yorùbá tí ó yege.

Èmi Ọ̀jọ̀gbọ́n Wándé Abímbọ́lá fi tayọ̀ tayọ̀ júwe ìwé yìí gẹ́gẹ́ bíìwé tí a lè kà ní ilé ẹ̀kọ́ Girama tàbí Yunifásítì, mo sì kí Akọ́dá Awo Ìlú Ìbàdàn kú oríire, èyí kò ní jẹ́ àkọmọ, a ó kọ òmíràn, a ó sì rí ẹ̀mí lò ó, àlékún owó, àlékún ọmọ, àlékún àìkú baálẹ̀ ọrọ̀.

Author: Oloye Odegbola Ifalere
Reviewer: Dr. Faleye
No. of Pages: 724
Amount: #25,000.00 $100.00  
 
Order Now!

View More Publications

 

 

Contact Address

Stay in Touch

Distributors Contacts

12, Falere Odegbola Street, Off Alakaso Road,

Omi-Adio, Ibadan, Ido LGA, Oyo State, Nigeria.

Phone No: +2348054009431, +2347034208381

Email: info@odegbolaifalere.com

Website: www.odegbolaifalere.com

=> OAJ Book shop Dugbe, Ibadan, Oyo State. +2349189747423

=> Otunba Lekan Ajirotutu, NTA Ch 10, Lagos State.

=> Tubosun Oladapo, Lagos Garage, Iwo Road, Ibadan, Oyo State.

=> Odusote Book Shop, Oke-Bola, Ibadan.

 

=> Deji Medubi, UNILAG, Lagos State.

=> Ejiodi Home of Tradition, Alade Near Moniya, Ibadan, Oyo State.

=> Dr. Adeola Faleye, OAU Ile-Ife, Osun State.

=> Dr. Abiodun Agboola, OAU Ile-Ife, Osun State.

=> OAU Bookshop, Ile-Ife, Osun State.

=> U.I Bookshop Ibadan, Oyo State. 

=> 13, Elebuibon Street, Osogbo, Osun State

Subscribe to our Newsletter

Navigation