Isẹ́ tí Olóyè Ọdẹ́gbọlá Ifálérè Ọdẹ́gbèmí ńṣe

 • Babaláwo tí ó ń dáfá, tí ó ń ṣe ètùtù ni Ọdẹgbọla,
 • A máa dá ẹsẹ̀ńtáyé ọmọ,
 • Ifá títẹ̀,
 • Ìtọ́jú ààrùn ara ọmọdé àti àgbà.
 • abbl

 

A tún ńṣe

 • Iṣẹ́ Atẹ̀wétà (Publishing Firm)
 • Ọdẹgbọla Computer Centre
 • À ń ra ilẹ̀, a sì tún ńta ilẹ (Land Purchase and Sale)

 

Àwọn Ìwé ó tí Kọ Jáde

- Ìbágbépọ̀ Tọkọ Taya, 2014.

Ó dá lórí pàtàkì ìgbéyàwó àti ọ̀nà tí ìgbéyàwó kò fi ní máa túká mọ́.

 

- Ìwé Mímọ́ Ifá Ẹ̀sìn Àkọ́dá,

Èyi ni ìwé pàtàkì tí ó ní ẹsẹ méjì méjì lórí odù kọ̀ọ̀kan tí ó kó gbogbo odù já pátápátá tí ó sì pàsẹ ifá dáadáa, tí ó yéni yékéyéké tí ó sì ní àkọtọ́ èdè Yorùbá tí ó yege.

 

Ìwé tí ó ńbọ̀ lọ́nà

 • Ọ̀kan náà kọ́
 • Òjísẹ́ ni òrìsà
 • àti bẹẹbẹẹlọ
 

Contact Address

Stay in Touch

Distributors Contacts

12, Falere Odegbola Street, Off Alakaso Road,

Omi-Adio, Ibadan, Ido LGA, Oyo State, Nigeria.

Phone No: +2348054009431, +2347034208381

Email: info@odegbolaifalere.com

Website: www.odegbolaifalere.com

=> OAJ Book shop Dugbe, Ibadan, Oyo State. +2349189747423

=> Otunba Lekan Ajirotutu, NTA Ch 10, Lagos State.

=> Tubosun Oladapo, Lagos Garage, Iwo Road, Ibadan, Oyo State.

=> Odusote Book Shop, Oke-Bola, Ibadan.

 

=> Deji Medubi, UNILAG, Lagos State.

=> Ejiodi Home of Tradition, Alade Near Moniya, Ibadan, Oyo State.

=> Dr. Adeola Faleye, OAU Ile-Ife, Osun State.

=> Dr. Abiodun Agboola, OAU Ile-Ife, Osun State.

=> OAU Bookshop, Ile-Ife, Osun State.

=> U.I Bookshop Ibadan, Oyo State. 

=> 13, Elebuibon Street, Osogbo, Osun State

Subscribe to our Newsletter

Navigation